
7f5198233a9d2cdc6006c395b4872f5e.ppt
- Количество слайдов: 19
Welcome to today’s service… Say to them that are of a fearful heart, be strong, fear not, behold, your God will come with vengeance, even God with a recompense; he will come and save you. – Isaiah 35:
1. Hymn 541 - Yoruba 1. Mo ti sina, sinu ese, Ore Oluwa lori mi he, Oku fun mi lori igi, Ore Ofe Oga Ogo poju. 2. Mo ti sonu, sinu ese, Ore Oluwa lori mi he, Oku fun mi lori igi, Ore Ofe Oga Ogo poju. 3. Halleluyah; Halleluyah Ore Oluwa lori mi he, Oku fun mi lori igi, Ore Ofe Oga Ogo poju. (Amin)
2. Hymn 387 – Yoruba (117 Eng) 1. Emi ba legberun ahon, Fiyin Olugbala Ogo Olorun oba mi, Isegun Ore re cr Abi ko seun fun o, A oma se fun mi Eje re se fun, Eje re se fun mi. 2. Jesu to soro mi dayo, Omu banuje tan Orin ‘yin lenu elese, Iye ati ilera cr Abi ko seun fun o, A oma se fun mi. 3. Baba mi at’Olorun mi, Fun mi ni ‘ranwo Re Ki nle ro ka gbogbo aiye, Lola oruko Re cr Abi ko seun fun o, A oma se fun mi. 4. O korin odi gbohun Re, A foju ri gbala Oniro binuje yo ayo, Ara e ho fayo cr Abi ko seun fun o, A oma se fun mi. (Amen)
Three members’ prayers… With God All Things Are Possible! -- Matthew 19: 26
3. Hymn 41 - English 1. Holy Spirit the Comforter 4. Oh Holy King, benefactor Descend into our midst Father send us blessings Thou are the King of blessing For thou art the Almighty We are expecting thee. Who blesses His children. 2. For thou art the Almighty King 5. King of mercy, O King of life Great King and benefactor Kindle thy light for us Oh King of spirit descend now Thou art the King full of light We are expecting thee. 3. King of mercy descend now 6. O Holy King, O King of light Look on us with mercy Descend and bless us now We thy children look unto thee For thou art King of mercy Open thy door of mercy. We are expecting thee. Amen
Silent Prayer Therefore I say to you, all things for which you pray and ask, believe that you have received them, and they will be granted you. -- Mark 11: 24
4. Hymn 537 – Yoruba 1. Ma foya ni apa Jesu, Ko si ohun eru kan, Ina ti njo ko le sun mo o, Ogun esu ti di wiwo mole. 2. Mo ro mo agbelebu Re Mo ka ohun gbogbo sasan Ma beru ire okan mi, Ayo nbe ninu eje Jesu. - OVER -
4. Hymn 537 – Yoruba (Cont’d) 3. Emi ko ni ju o sile, Jesu Olugbala mi, Ninu Re ni iye mi wa, Ire ni Olugbala mi. 4. Ijo Mimo bu si ayo, Oko iyawo wa pelu Re, Ayo ni tire si ma yo, Ade iye na yio je tire. Amin.
st 1 Bible Lesson Proverbs 11: 24 -31 Beat your plowshares into swords And your pruning hooks into spears; Let the weak say, "I am strong. "' – Joel 3: 10
5. Hymn 52 – Yoruba 1. Oluwa Olugbala, 3. E kepe Oba Ogo, Oluwa Olugbala, E kepe Oba Mimo, Jehovah Olugbala, E kepe Oba Iye Yio si gbo ti wa. Yio si gbo oro wa. 2. Oluwa Oba Iye 4. Oba ti ko gbagbe, Oluwa Oba Iye, Oba ti ko gbagbe, Kristi Oba Imole, Oba ti ko gbagbe, O mbe lodo wa. Ijo Mimo re. - OVER -
5. Hymn 52 – Yoruba 5. Awon Angeli mbe, 7. E ke Halleluya, Awon Angeli mbe, E ke Halleluya, Ninu ayo nla. Pelu ife Mimo. Amin. 6. Iyin fun Oba Mimo, Iyin fun Oba nla, Ogo ni fun Oba nla, Fun ise Re ni.
nd 2 Bible Lesson Luke 16: 19 -31 For it would have been better for them not to have known the way of righteousness, than having known it, to turn from the holy commandment delivered to them. – 2 Peter 2: 21
6. Hymn 303 - Yoruba 1. Eda to mola ko si, Asan laiye nse. 2. Imo asan ni t’aiye, Asan laiye nse. 3. Sagbeke le Oluwa, Sagbeke re le. Amin.
Church Announcements…
The Sermon… That if you confess with your mouth, "Jesus is Lord, " and believe in your heart that God has raised Him from the dead, you will be saved. -- Romans 10: 9
Collection… Please remember… All collections are taken ONCE, followed by tithes and Chairmanship!
Thanks Offering… Enter into His gates with thanksgiving, And into His courts with praise. Be thankful to Him, and bless His name. – Psalms 100: 4
7. Hymn 406 - Yoruba 1. Jehovah, Jesu Kristi, 3. Ninu okun pupa ni, Michael Mimo, Oga Farao at’ogun re, ogun, Parun laigberi mo, Ijo Mimo mbe niwaju Re, Fun isimi okan Israel, Teru tedun okan wa, Nigbati ‘reti dopin, Lati saferi Emi Mimo, Okun diyangbe ile, Ewa ogo Orun, Nipa agbara iyanu yi, Ibukun ati gbega, Sin wa de ‘nu iye. Ma se fi du wa. 4. Ogbon, Imo, Oye Re, 2. Ma bi si i, Si ma re si i, Gegebi ti Solomon, Ileri Re f’Abraham, Igbega ati igbala Niwoyi odun titun, Bi ti Josef’, Danieli, Iwo yio f’omo se re, Imisi a ‘tohun Orun, Ileri yi fun Sarah, Bi ti Paul, Samueli, Jo muse f’awon agan, Elmorijah, Olubukun, Ti nwon woju Re Baba, Se nwon ni ti ‘wa. OVER -
7. Hymn 406 - Yoruba 5. Awa nse ireti Re, Gege b’Omo ileri, Ajo jumo jogun iye, Ainipekun ‘joba orun, Wa f’Emi orun s’atoko, Di wa l’amure agbara, Ka sise lailabawon, Si iye ainipekun. Amin.